Ijewo: Ex. 14 vs.13-14, Rom.8 vs.31, 2Tim.4 vs.18
Orin Iyin / Ijosin
Koko Adura

1. E dupe lowo Olorun wipe owo Re yoo se ohun iyanu ninu aye yin.
2. E dupe lowo Re nitori lakoko yi li a o fi ogo ati agbara Re han lara yin.
3. Nipa eje Jesu, a dide lodi si gbogbo ifisun ati idalebi ota a si fagile loruko Jesu.
4. Gbogbo ibi ti nfohun ni ipile aye wa, gba ibewo iku nipa ina Olorun loruko Jesu.
5. Ipile aye wa, si ki osi gba ina idande loruko Jesu.
6. Olorun alagbara, dide ki o si gba wa lowo ota wa alagbara loruko Jesu.
7. Gbogbo iranse ibi to duro bi okunrin alagbara lodi si iloyun ati ibimo wa, orun ke o lule
loni loruko Jesu.
8. Eyin irugbin iyagan ninu awon eya ile omo wa, e gbo oro Oluwa, e fatu pelu gbongbo
yin loruko Jesu.
9. Eyin asepari ota olojo pipe, loni e di yiyo nipa ina loruko Jesu.
10. Ina idande Olorun o, be gbogbo eya ile omo wa wo ati ago ara wa lapapo fun itusile
nla loruko Jesu.
11. Gbogbo gbolohun ti a ti so ninu okunkun eyi ti o ndena oyun nini, orun fagile o loni
loruko Jesu.
12. Ofa iyagan, o ki nse ipin wa, pada si bi to ti wa loruko Jesu.
13. Agbara to lana si ori okun pupa ni ojo wonni, be wa wo fun iloyun ati ibimo layo ati
alafia loruko Jesu.
Ki oko ki o gbowo le nkan omokunrin re nigbati iyawo gbe owo le ile omo re, lati
gba koko adura 14 -17.
14. Iwo ile omo mi gbo oro Oluwa si fun iloyun loruko Jesu.
15. Eyin eya ile omo mi, e gba ifowokan ati orun wa ki a si mu yin larada loruko Jesu.
16. Iwo egun ti o lodi si iloyun, eyiti o nja awon eya ile omo mi logun, fo /3x, loruko Jesu.
17. Oluwa wo mi san emi o san, Oluwa gba mi la emi o la.
18. Orun iloyun wa, akoko to, si ni oruko Jesu.
19. E dupe lowo Olorun fun idahun adura

Share/Print:
×

Prayers Or Counselling?

Live Chat with our Ministers on WhatsApp

× Prayers/Counselling